Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #106 Translated in Yoruba

يَوْمَ تَبْيَضُّ وُجُوهٌ وَتَسْوَدُّ وُجُوهٌ ۚ فَأَمَّا الَّذِينَ اسْوَدَّتْ وُجُوهُهُمْ أَكَفَرْتُمْ بَعْدَ إِيمَانِكُمْ فَذُوقُوا الْعَذَابَ بِمَا كُنْتُمْ تَكْفُرُونَ
Ni ojo ti awon oju kan yoo funfun (imole). Awon oju kan yo si dudu. Ni ti awon ti oju won dudu, (A o bi won pe:) "Se e sai gbagbo leyin igbagbo yin ni?" Nitori naa, e to iya wo nitori pe e sai gbagbo

Choose other languages: