Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #173 Translated in Yoruba

الَّذِينَ قَالَ لَهُمُ النَّاسُ إِنَّ النَّاسَ قَدْ جَمَعُوا لَكُمْ فَاخْشَوْهُمْ فَزَادَهُمْ إِيمَانًا وَقَالُوا حَسْبُنَا اللَّهُ وَنِعْمَ الْوَكِيلُ
(Awon ni) awon ti awon eniyan wi fun pe: “Won ma ti kora jo de yin, nitori naa e beru won.” (Eyi) lekun igbagbo ododo won. Won si so pe: “Allahu to fun wa. O si dara ni Alamoojuto.”

Choose other languages: