Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #40 Translated in Yoruba

قَالَ رَبِّ أَنَّىٰ يَكُونُ لِي غُلَامٌ وَقَدْ بَلَغَنِيَ الْكِبَرُ وَامْرَأَتِي عَاقِرٌ ۖ قَالَ كَذَٰلِكَ اللَّهُ يَفْعَلُ مَا يَشَاءُ
(Zakariyya) so pe: “Oluwa mi, bawo ni emi yoo se ni omokunrin; mo ma ti dagbalagba, agan si ni obinrin mi?” (Molaika) so pe: “Bayen ni Allahu se n se ohun ti O ba fe.”

Choose other languages: