Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #68 Translated in Yoruba

إِنَّ أَوْلَى النَّاسِ بِإِبْرَاهِيمَ لَلَّذِينَ اتَّبَعُوهُ وَهَٰذَا النَّبِيُّ وَالَّذِينَ آمَنُوا ۗ وَاللَّهُ وَلِيُّ الْمُؤْمِنِينَ
Dajudaju awon eniyan t’o sunmo (Anabi) ’Ibrohim julo ni awon t’o tele e ati Anabi yii (Anabi Muhammad s.a.w.) ati awon t’o gbagbo ni ododo. Allahu ni Alatileyin fun awon onigbagbo ododo

Choose other languages: