Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #72 Translated in Yoruba

وَقَالَتْ طَائِفَةٌ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ آمِنُوا بِالَّذِي أُنْزِلَ عَلَى الَّذِينَ آمَنُوا وَجْهَ النَّهَارِ وَاكْفُرُوا آخِرَهُ لَعَلَّهُمْ يَرْجِعُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab wi pe: “E lo gbagbo ninu ohun ti Won sokale fun awon t’o gbagbo ni ododo nibere ojo, ki e si tako o nipari re, boya awon musulumi (kan) maa seri pada (seyin ninu esin ’Islam)

Choose other languages: