Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayah #86 Translated in Yoruba

كَيْفَ يَهْدِي اللَّهُ قَوْمًا كَفَرُوا بَعْدَ إِيمَانِهِمْ وَشَهِدُوا أَنَّ الرَّسُولَ حَقٌّ وَجَاءَهُمُ الْبَيِّنَاتُ ۚ وَاللَّهُ لَا يَهْدِي الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ
Bawo ni Allahu yo se fi ona mo ijo kan t’o sai gbagbo leyin igbagbo won? Won si jerii pe dajudaju Ojise naa, ododo ni. Awon eri t’o yanju si ti de ba won. Allahu ki i fi ona mo ijo alabosi

Choose other languages: