Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Translated in Yoruba

وَالذَّارِيَاتِ ذَرْوًا
(Allahu bura pelu) ategun t’o n tu erupe jade nile taara
فَالْحَامِلَاتِ وِقْرًا
(O bura pelu) awon esujo t’o wuwo rinrin
فَالْجَارِيَاتِ يُسْرًا
(O bura pelu) awon oko oju-omi t’o n rin pelu irorun
فَالْمُقَسِّمَاتِ أَمْرًا
(O bura pelu) awon molaika t’o n pin nnkan (ti O ti pin fun eda)
إِنَّمَا تُوعَدُونَ لَصَادِقٌ
Ododo ma ni ohun ti A n se ni adehun fun yin
وَإِنَّ الدِّينَ لَوَاقِعٌ
Ati pe dajudaju Ojo Esan maa sele
وَالسَّمَاءِ ذَاتِ الْحُبُكِ
(Allahu tun bura pelu) sanmo olosoo
إِنَّكُمْ لَفِي قَوْلٍ مُخْتَلِفٍ
Dajudaju eyin wa lori oro t’o n takora won (nipa al-Ƙur’an)
يُؤْفَكُ عَنْهُ مَنْ أُفِكَ
Eni ti won n se lori kuro nibi al-Ƙur’an ni eni ti Won ti se lori kuro nibe (lati inu Laohul-Mahfuth)
قُتِلَ الْخَرَّاصُونَ
Egbe ni fun awon opuro
Load More