Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Asr Ayah #3 Translated in Yoruba

إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَتَوَاصَوْا بِالْحَقِّ وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ
Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won so asotele ododo laaarin ara won, ti won si tun so asotele suuru laaarin ara won

Choose other languages: