Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Balad Translated in Yoruba

لَا أُقْسِمُ بِهَٰذَا الْبَلَدِ
Emi (Allahu) bura pelu ilu yii
وَأَنْتَ حِلٌّ بِهَٰذَا الْبَلَدِ
Iwo si ni eto si ilu yii (lati jagun ninu re)
وَوَالِدٍ وَمَا وَلَدَ
(Mo tun) bura pelu obi ati ohun t’o bi
لَقَدْ خَلَقْنَا الْإِنْسَانَ فِي كَبَدٍ
Dajudaju A seda eniyan sinu isoro
أَيَحْسَبُ أَنْ لَنْ يَقْدِرَ عَلَيْهِ أَحَدٌ
Se o n lero pe eni kan ko ni agbara lori oun ni
يَقُولُ أَهْلَكْتُ مَالًا لُبَدًا
O (si) n wi pe: "Emi ti bana dukia opolopo (lati fi tako Anabi s.a.w)
أَيَحْسَبُ أَنْ لَمْ يَرَهُ أَحَدٌ
Se o n lero pe eni kan ko ri oun ni
أَلَمْ نَجْعَلْ لَهُ عَيْنَيْنِ
Se A ko se oju meji fun un
وَلِسَانًا وَشَفَتَيْنِ
Ati ahon pelu ete meji (ti A se fun un)
وَهَدَيْنَاهُ النَّجْدَيْنِ
A si fi ona meji mo on
Load More
0:00 0:00
Al-Balad : 1
Mishari Rashid al-`Afasy