Surah Al-Fatiha Translated in Yoruba
إِيَّاكَ نَعْبُدُ وَإِيَّاكَ نَسْتَعِينُ
Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si
اهْدِنَا الصِّرَاطَ الْمُسْتَقِيمَ
Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ
ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara)