Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Hadid Ayah #21 Translated in Yoruba

سَابِقُوا إِلَىٰ مَغْفِرَةٍ مِنْ رَبِّكُمْ وَجَنَّةٍ عَرْضُهَا كَعَرْضِ السَّمَاءِ وَالْأَرْضِ أُعِدَّتْ لِلَّذِينَ آمَنُوا بِاللَّهِ وَرُسُلِهِ ۚ ذَٰلِكَ فَضْلُ اللَّهِ يُؤْتِيهِ مَنْ يَشَاءُ ۚ وَاللَّهُ ذُو الْفَضْلِ الْعَظِيمِ
E yara lo sibi aforijin lati odo Oluwa yin ati Ogba Idera ti fife re da bi fife sanmo ati ile. Won pa a lese sile de awon t’o gbagbo ninu Allahu ati awon Ojise Re. Iyen ni oore ajulo Allahu ti O n fun eni ti O ba fe. Allahu si ni Oloore nla

Choose other languages: