Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Isra Ayah #103 Translated in Yoruba

فَأَرَادَ أَنْ يَسْتَفِزَّهُمْ مِنَ الْأَرْضِ فَأَغْرَقْنَاهُ وَمَنْ مَعَهُ جَمِيعًا
Nitori naa, (Fir‘aon) fe ko won laya je lori ile. A si te oun ati awon t’o wa pelu re ri patapata

Choose other languages: