Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Maun Translated in Yoruba

أَرَأَيْتَ الَّذِي يُكَذِّبُ بِالدِّينِ
So fun mi nipa eni t’o n pe Ojo Esan niro
فَذَٰلِكَ الَّذِي يَدُعُّ الْيَتِيمَ
Iyen ni eni t’o n le omo-orukan danu
وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ الْمِسْكِينِ
Ko si nii gbiyanju lati bo mekunnu
فَوَيْلٌ لِلْمُصَلِّينَ
Egbe ni fun awon (munaafiki) t’o n kirun; ko tumo si “ohun t’o n run eniyan”. Amo itumo “irun” ni “ohun t’o n run ese olukirun” nitori pe ti olukirun ba ti se aluwala ni o ti san gbogbo awon ese weere ti o ti fi awon orikee ara re se siwaju. Bakan naa
الَّذِينَ هُمْ عَنْ صَلَاتِهِمْ سَاهُونَ
awon t’o n gbagbe lati kirun won ni asiko re
الَّذِينَ هُمْ يُرَاءُونَ
awon t’o n se sekarimi
وَيَمْنَعُونَ الْمَاعُونَ
ati pe won n hanna ohun elo (fun awon eniyan)