Surah An-Nasr Translated in Yoruba

إِذَا جَاءَ نَصْرُ اللَّهِ وَالْفَتْحُ

Nigba ti aranse Allahu (lori ota esin) ati sisi ilu (Mokkah) ba sele
وَرَأَيْتَ النَّاسَ يَدْخُلُونَ فِي دِينِ اللَّهِ أَفْوَاجًا

ti o si ri awon eniyan ti won wonu esin Allahu nijonijo
فَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ وَاسْتَغْفِرْهُ ۚ إِنَّهُ كَانَ تَوَّابًا

nitori naa, safomo pelu idupe fun Oluwa re. Ki o si toro aforijin lodo Re. Dajudaju O n je Olugba-ironupiwada