Surah An-Nisa Ayah #159 Translated in Yoruba
وَإِنْ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ إِلَّا لَيُؤْمِنَنَّ بِهِ قَبْلَ مَوْتِهِ ۖ وَيَوْمَ الْقِيَامَةِ يَكُونُ عَلَيْهِمْ شَهِيدًا

Ko si nii si eni kan ninu awon ahlul-kitab (laye nigba ti ‘Isa ba sokale pada lati oju sanmo) afi ki o gba a gbo ni ododo siwaju iku re. Ni Ojo Ajinde, o si maa je elerii lori won. agbega ipo gege bi eyi t’o jeyo ninu surah Al-’a‘rof; 7:176 ati surah Moryam; 19:57) tabi ki o tumo si agbega tara (iyen gbigbe ara kuro lati aye isale si aye oke gege bi eyi t’o jeyo ninu surah Fatir; 35:10). Amo ko ni tabi-sugbon ninu mo pe nigbakigba ti harafi “إلى” ba ti tele “رفع” oke sanmo keje ni Allahu wa nitori pe inu sanmo yii naa ni Anabi wa Muhammad (sollalahu alayhi wa sallam) gun lo lati lo gba irun wakati marun-un wa lodo Allahu (subhanahu wa ta’ala) lasiko irin oru ati igun-sanmo gege bi Allahu se fi rinle ni ibere surah al-’Isro’. Koda tohun ti bi aigbagbo Fir‘aon se gbopon to o kuku gba pe sanmo ni Allahu (subhanahu wa ta’ala) wa. O si be Hamon ni ile giga fiofio ko. O fe yoju wo Allahu! (surah al-Ƙosos; 28:38). Nitori naa
Choose other languages:

Albanian

Amharic

Azerbaijani

Bengali

Bosnian

Bulgarian

Burmese

Chinese

Danish

Dutch

English

Farsi

Filipino

French

Fulah

German

Gujarati

Hausa

Hindi

Indonesian

Italian

Japanese

Jawa

Kazakh

Khmer

Korean

Kurdish

Kyrgyz

Malay

Malayalam

Norwegian

Pashto

Persian

Polish

Portuguese

Punjabi

Russian

Sindhi

Sinhalese

Somali

Spanish

Swahili

Swedish

Tajik

Tamil

Tatar

Telugu

Thai

Turkish

Urdu

Uyghur

Uzbek

Vietnamese

Yoruba