Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayah #175 Translated in Yoruba

فَأَمَّا الَّذِينَ آمَنُوا بِاللَّهِ وَاعْتَصَمُوا بِهِ فَسَيُدْخِلُهُمْ فِي رَحْمَةٍ مِنْهُ وَفَضْلٍ وَيَهْدِيهِمْ إِلَيْهِ صِرَاطًا مُسْتَقِيمًا
Ni ti awon t’o gbagbo ninu Allahu, ti won si duro sinsin ti I, O maa fi won sinu ike ati ola kan lati odo Re. O si maa fi won mo ona taara si odo Re

Choose other languages: