Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Translated in Yoruba

الرَّحْمَٰنُ
Ajoke-aye
عَلَّمَ الْقُرْآنَ
O fi imo al-Ƙur’an mo (eni ti O fe)
خَلَقَ الْإِنْسَانَ
O seda eniyan
عَلَّمَهُ الْبَيَانَ
O si fi alaye (oro siso) mo on
الشَّمْسُ وَالْقَمَرُ بِحُسْبَانٍ
Oorun ati osupa (n rin) fun isiro (ojo aye)
وَالنَّجْمُ وَالشَّجَرُ يَسْجُدَانِ
Awon itakun ile ati igi n fori kanle (fun Allahu)
وَالسَّمَاءَ رَفَعَهَا وَوَضَعَ الْمِيزَانَ
Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon ofin deede lele (fun eda)
أَلَّا تَطْغَوْا فِي الْمِيزَانِ
pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon
وَأَقِيمُوا الْوَزْنَ بِالْقِسْطِ وَلَا تُخْسِرُوا الْمِيزَانَ
E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
وَالْأَرْضَ وَضَعَهَا لِلْأَنَامِ
Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
Load More