Surah At-Takathur Translated in Yoruba

كَلَّا لَوْ تَعْلَمُونَ عِلْمَ الْيَقِينِ

Bee ni, ti o ba je pe e ni imo amodaju ni (eyin iba ti se bee)
ثُمَّ لَتُسْأَلُنَّ يَوْمَئِذٍ عَنِ النَّعِيمِ

Leyin naa, dajudaju ni ojo yen won maa bi yin leere nipa igbadun (aye yii)