Surah Quraish Translated in Yoruba

إِيلَافِهِمْ رِحْلَةَ الشِّتَاءِ وَالصَّيْفِ

(Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru
الَّذِي أَطْعَمَهُمْ مِنْ جُوعٍ وَآمَنَهُمْ مِنْ خَوْفٍ

Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya